Àwọn àbá wà ní ìrísì ní OneNote

Gba ́ẹ̀dà fáìlì ìfilọ́ĺẹ̀ síĺẹ̀

Gbàsílẹ̀


Ó rọrùn láti sún láti Evernote lọsí OneNote kí o sì múdọ́gba àwọn afikọ̀wé rẹ lóri gbogbo àwọn ohun èlò, fún ọ̀fẹ́. Ṣàwárí bí ó ṣe jẹ́


Ṣẹ̀dá ní ọ̀nà tìrẹ

Ǹjẹ̀ o kọ àwọn àbá tó nílá lóri aṣọ ìnuwọ́ sílẹ̀ tàbí Àwọn àkíyèsí àlẹ̀mọ́? Ṣé Ṣegẹ́gẹ́ kíkún jẹ́ àrà rẹ? OneNote ti dára fún ẹ lọ́nà kan nà tí o ṣe ìrísí àwọn èrò rẹ. Tẹ, kọ tàbí fiyàwòrán pẹ̀lú ọ̀fẹ́ èrò ti gègé sí pépà. Ṣàwárí kí o sì tẹ̀mọ́lẹ̀ láti wẹ́ẹ̀bù sí àwọn àbá àwòrán.

Kọ̀ǹpútà Alogègé kan tó ń ṣàfihàn OneNote lórí Windows 10

Ìbáṣiṣẹ́pọ̀ pẹ̀lú ẹnikẹ́ni

Àjọṣepọ̀ rẹ ṣẹ́gun àbá ti century. Ẹbí rẹ ṣètò mẹ́nù fún ríyúníọ̀nù. Dúró lórí ojú ìwé kanná kí o dẹ̀ múdọ́gba níbikíbi tí o bá wà.

Àwòrán ẹnìkan ní lílo OneNote lórí kọ̀ǹpútà alogègé fún iṣẹ́

Ronú pẹ̀lú yíìnkì

Ṣetán. Ọ̀wọ̀. Àfiyàwòrán. kálàmù kan tàbí etí ìka ọwón ní irinṣẹ́ tí o nílò nìkan. Gba àwọn àkíyèsí àfọwọ́kọ kí o sì yíwọn padà sí àyọkà tí a tẹ̀ tóbáyá. sṢàgbéyọ ǹkan tí ó bá ṣe pàtàkì kí o sì sọ àwọn àbá pẹ̀lú àwọn àwọ̀ tàbí àwọn ìrísí.

Àwọn àwọ̀ ìmọ́lẹ̀ tí a fiyàwòrán nípasẹ̀ Kálàmù Surface

Ìráyèsí láti ibikíbi

Gbà àkíyèsí. Ó rọrùn láti fa àkóónú rẹ láti níbikíbi, kódà tí o bá wá ní àìsílóníforíkorí. Bẹ̀rẹ̀ lórí àgbélétan kí o sì ṣàfikún àwọn àkíyèsí lórí fóónù rẹ. OneNote ṣiṣẹ́ lórí èyíkèyí ohun èlò tàbí pẹpẹ.

Àwòrán ti OneNote ṣàfihàn lórí ipad, iphone àti Apple Watch
Dára pẹ̀lú Office

OneNote jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ ebí Office tí o ti mọ̀ tẹ́lẹ̀. Ṣe ìrísí àwọn afikọ̀wé pẹ̀lú àwọn kókó tí a fà jáde kúrò ní í meélì Outlook, fibọ̀ Excel table kan. Mú púpọ̀ ní ṣíṣe pẹ̀lú ààyò àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀ Office tó ṣiṣẹ́ pọ̀.

Àwòrán ti ilé Ibi iṣẹ́ kan

Sopọ̀ nínu iyàrá ìkàwé

Mú àwọn akẹ́ẹ̀kọ́ papọ̀ ní àyè Ìbáṣiṣẹ́pọ̀ tàbí fún oníkálùkù ní àtílẹyìn ní àwọn afikàkọ̀wé àdáni. Kò sí ìtèwé àwọn ìwé ìléwọ́. O lè to àwọn ìkẹ́kọ̀ọ́ kí o dẹ̀ pín àwọn ìṣẹ́ àmúrelé láti àpapọ̀ àkóónú ibi ìpamọ́.

Ṣàwárí afikọ̀wé Kílàsì

Àwòrán ti OneNote ṣàfihàn lórí Surface Book